Aya Femi Gbajabiamila dira fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àádọ́ta ọdún Olayemi Oniroyin 5/28/2018 05:37:00 pm Add Comment Edit Adari ọmọ ẹgbẹ́ to pọ̀ jù lọ nílé ìgbìmọ̀ aṣojú sofin Abuja, Femi Gbaja ṣe ajọyọ pẹ̀lú aya rẹ, Yemisi Gbaja, pẹ̀lú bo se pe ẹni àádọ́ta ọdún... Read More
Ká mú tẹ̀gàn kúrò, Telu rẹwà lọkunrin Olayemi Oniroyin 5/27/2018 02:25:00 pm Add Comment Edit Kò sí ohun tó burú láti nawọ́ ìfẹ́ si àwọn ẹ̀yà to kú lórílẹ̀ Nàìjíríà 🇳🇬 , sebi ọkàn náà ni gbogbo wa. Ṣùgbọ́n gẹ́g... Read More
Ohun tí Muyiwa Ademola sọ nípa orekelẹwa aya rẹ ni yìí Olayemi Oniroyin 5/17/2018 07:00:00 pm Add Comment Edit "Olólùfẹ́ mi, aya mi, Akankẹ mi, bí mo bá wà sílè ilé ayé nígbà igba, ìwọ kan náà lọ má jẹ aya mi. Àìmọye ìdùnnú lọ fún mi ti mi ò lé r... Read More
Oludasilẹ Facebook, Mark Zuckerberg pé ẹni ọdún mẹ́rinlelọgbon (34) lónìí Olayemi Oniroyin 5/17/2018 10:25:00 am Add Comment Edit Òní, 17/05/18, ni ọjọ́ ìbí oludasile Facebook, Mark Zuckerberg, eléyìí tí gbogbo wa njẹ àǹfààní rẹ lónìí. Kí n tó kí Mark fún ayẹyẹ ọjọ́ ì... Read More
Happy Birthday Oluwafunke Etti Olayemi Oniroyin 4/25/2018 12:37:00 pm Add Comment Edit Òní ni ọjọ́ ìbí osere òní tíátà, Funke Etti. Igba ọdún, ọdún kan ni. Àṣẹ Read More
Happy Birthday olùkọ́ mi: Apènà pé léèyàn Olayemi Oniroyin 4/12/2018 09:04:00 am Add Comment Edit Ẹ bá ma kí Apena, ẹ bá mi sọ fún olùkọ́ mi wí pé Olayemi mo wọn léèyàn pàtàkì. Bí ó bá lo igba ọdún láyé, ọdún kan ni wọn o fi ka fún ọ lóde... Read More
Happy Birthday! Mama Kunle Afolayan pé ní ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) Olayemi Oniroyin 4/03/2018 07:59:00 am 1 Comment Edit Mama Kunle Afolayan pé ẹni odùn márùndínlọ́gọ́rin láyé. A gbàdúrà ire àlàáfíà, ìdùnnú àti èmi gigùn fún mama. Igba ọdún, ọdún kan ni. Ha... Read More
O ti jasire: Bukola Oni tí diyàwó tuntun Olayemi Oniroyin 3/30/2018 07:55:00 pm Add Comment Edit Mi ò lọrẹ to pò, díẹ ni àwọn ọrẹ mi; lára wọn sì ni Bukky wá. Bukky a má lo inú kan, ó nifẹ àwọn ènìyàn, bákan ló jẹ́ akíkanjú obìnrin. Mo... Read More
Ènìyàn bí Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi Olayemi Oniroyin 3/30/2018 08:56:00 am Add Comment Edit Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi, adari ijo Love Of Christ Generation C&S to wá ni Clapham nílùú London ni ènìyàn pàtàkì wa fún ọsẹ ... Read More
#HappyBirthday Joke Muyiwa: Olùkọ́ àgbà iṣẹ́ tíátà tó pedegé! Olayemi Oniroyin 3/21/2018 01:47:00 pm 9 Comments Edit Àyàfi ti ènìyàn bá fẹ fi gba kan bọkan nínú ni yóò sọ wí pé Joke Muyiwa kii se agbaoje nínú ìṣe tíátà. Se àgbékalẹ̀ ni ka sọ ní àbí èdè líl... Read More
Áńgẹ́lì kan tí ń jẹ Lára Olubo Olayemi Oniroyin 3/15/2018 04:05:00 pm Add Comment Edit Òní, 15/03/18, ní ọjọ́ ìbí ogbontarigi sọrọsọrọ orí afẹ́fẹ́, Lára Olubo. Arábìnrin Lara jẹ́ akíkanjú ènìyàn eléyìí tí kìí fi ìṣe rẹ ṣeré. ... Read More
#HappyBirthday Aduke: Adenike tí gòkè odò káfárá to ja! Olayemi Oniroyin 3/14/2018 01:22:00 am Add Comment Edit Olójú ènìyàn tó pé láì lábùkù. Olójú onisẹ ọpọlọ tí ò kù síbì kan . Àyàfi ẹni Oluwa bá dalọla. Ayafi Aduke t'Èdùmàrè gbé ga lójijì. ... Read More
Happy Birthday Prof: Ènìyàn bí Yemi Osinbajo wón bí oju Olayemi Oniroyin 3/08/2018 12:50:00 pm Add Comment Edit E má jẹ ki n parọ fún yín. Lára ona kan pàtàkì lati se àkíyèsí bóyá ènìyàn jẹ ọlọ́gbọ́n tàbí bẹẹkọ ni nípa fi fún ẹni bẹẹ láàyè láti sọ ọrọ ... Read More
Happy Birthday Prof: Ènìyàn bí Yemi Osinbajo wón bí oju Olayemi Oniroyin 3/08/2018 12:50:00 pm Add Comment Edit E má jẹ ki n parọ fún yín. Lára ona kan pàtàkì lati se àkíyèsí bóyá ènìyàn jẹ ọlọ́gbọ́n tàbí bẹẹkọ ni nípa fi fún ẹni bẹẹ láàyè láti sọ ọrọ ... Read More
"Ìdí tí oṣù kejì ọdún fi ṣe pàtàkì sì mi" - Olajumoke ọmọ oniburedi Olayemi Oniroyin 2/25/2018 04:11:00 pm Add Comment Edit "Oṣù kejì ọdún je àkókò ìyanu àti àgbàrá Ọlọ́run láyé mi. Nínú oṣù yìí ni ori gbemi pade TY Bello to fi Camera 📸 rẹ gbà os... Read More
#HappyBirthday Afeez Eniola Onílé Eré Olayemi Oniroyin 2/22/2018 07:46:00 am Add Comment Edit Èdùmàrè lo ń gbé ènìyàn ga, ọgbọ́n orí kọ. Ẹni mbẹ laye kò dúpẹ́, àìmọye ènìyàn rere tó sún ni ó jí. Gbogbo wa là bá Afeez Eniola yo lónìí... Read More
Ènìyàn pàtàkì bí Lara Olubo: Ọbabirin Sorosoro Agbaye Olayemi Oniroyin 2/01/2018 12:43:00 pm Add Comment Edit Bí ènìyàn bá semi loore mo ti ṣèlérí wí pé mi ò ní gbàgbé. Ọjọ́ tí mo n wà ènìyàn kan ṣoṣo láti dúró fún mi. Lara Olubo dúró fún mi lọ́nà m... Read More
Òní ni ojo ibi Dúpẹ́ Odulate ìyàwó Babatee Olayemi Oniroyin 2/01/2018 09:57:00 am Add Comment Edit Aya rere lọọdẹ ọkọ. #HappyBirthday Read More
#HappyBirthday Yinka Ayefele Ọba Tungba Gospel Olayemi Oniroyin 2/01/2018 08:35:00 am Add Comment Edit Olayinka Joel Ayefele le lodun lónìí ọjọ́ kinni oṣù kejì ọdún. Igba ọdún, ọdún kan ni. Ire. Read More
#HappyBirthday Yemi Sholade Agba Akin Olayemi Oniroyin 2/01/2018 06:57:00 am Add Comment Edit Gbogbo wa là bá Ogbeni Yemi Sholade yọ pelu bí osere náà ṣe lè lọ́dún. Ìgbà ọdún, ọdún kan ni. Àṣẹ Read More